Bi gbogbo agbaye ṣe n ṣe ajọyọ ayajọ awọn baba, iyẹn ‘Father’s day’, Gbajumọ akọrin takasufe, Davido ti sọ pe iṣoro nla ni ayẹyẹ ayajọ awọn baba ti ọdun yii jẹ fun oun. Davido sọ eyi ninu awọn atẹjade ...